[00:35.65] Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e [00:45.78] Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e [01:05.03] Iwa omo ni omo se ki n gbe [01:12.49] E to ju e da da [01:20.05] Iwa to ni ba dun, bami to ju e da da (da da) [01:34.96] Iwa yi lo soro [01:40.91] Lo se oun gbogbo ni mere mere banta [01:45.58] N ba to ju e [01:54.67] Iwa ni o ku oniwa ti o ba ti si anybody mo [02:05.19] Iwa se pataki (pataki) [02:14.42] A de le ba eni won ko n le [02:17.41] E kole bi iwa eni ni [02:22.22] Oniwa lo ni wa o [02:28.19] Iwa omo ni mu omo so ki ngbe [02:34.46] O ba dakun to ju e da da [02:36.12] Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e [02:41.63] Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e [03:18.25] Ara banbi jaye oba [03:20.30] Sope ijo ti ya fun orogbo [03:26.51] Ara banbi jaye oba [03:29.64] Sope ijo ti ya fun orogbo [03:36.70] E ki olukosun ayana ina [03:38.94] Sango ijo ti ya fun orogbo [03:42.72] Afi ni fun jo bomo loju oko oya [03:45.77] Sango ijo ti ya fun orogbo [03:50.71] Ko jeun ajanaku ma fi iyo si [03:52.93] Sango ijo ti ya fun orogbo [03:57.02] E fufu lele ya gi mo aya apata [03:59.83] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:03.71] Bi o wo odo ariwo ata [04:06.54] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:11.48] Bi o gun oke odo ariwo ata [04:13.20] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:17.59] Ko fese mejeji damiru oko oya [04:20.38] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:24.45] Awa na ti ri oba koso [04:27.55] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:31.69] E ki olukosun ayana ina [04:34.44] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:38.71] E ba mi ki olukoso ayana ina [04:40.69] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:43.65] Ara banbi jaye oba [04:45.22] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:48.02] Ara banbi jaye oba [04:50.34] Sango ijo ti ya fun orogbo [04:55.78]