Iwalewa

Song Iwalewa
Artist K1 De Ultimate
Album The Ultimate Collection

Lyrics

[00:35.65] Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e
[00:45.78] Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e
[01:05.03] Iwa omo ni omo se ki n gbe
[01:12.49] E to ju e da da
[01:20.05] Iwa to ni ba dun, bami to ju e da da (da da)
[01:34.96] Iwa yi lo soro
[01:40.91] Lo se oun gbogbo ni mere mere banta
[01:45.58] N ba to ju e
[01:54.67] Iwa ni o ku oniwa ti o ba ti si anybody mo
[02:05.19] Iwa se pataki (pataki)
[02:14.42] A de le ba eni won ko n le
[02:17.41] E kole bi iwa eni ni
[02:22.22] Oniwa lo ni wa o
[02:28.19] Iwa omo ni mu omo so ki ngbe
[02:34.46] O ba dakun to ju e da da
[02:36.12] Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e
[02:41.63] Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e
[03:18.25] Ara banbi jaye oba
[03:20.30] Sope ijo ti ya fun orogbo
[03:26.51] Ara banbi jaye oba
[03:29.64] Sope ijo ti ya fun orogbo
[03:36.70] E ki olukosun ayana ina
[03:38.94] Sango ijo ti ya fun orogbo
[03:42.72] Afi ni fun jo bomo loju oko oya
[03:45.77] Sango ijo ti ya fun orogbo
[03:50.71] Ko jeun ajanaku ma fi iyo si
[03:52.93] Sango ijo ti ya fun orogbo
[03:57.02] E fufu lele ya gi mo aya apata
[03:59.83] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:03.71] Bi o wo odo ariwo ata
[04:06.54] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:11.48] Bi o gun oke odo ariwo ata
[04:13.20] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:17.59] Ko fese mejeji damiru oko oya
[04:20.38] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:24.45] Awa na ti ri oba koso
[04:27.55] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:31.69] E ki olukosun ayana ina
[04:34.44] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:38.71] E ba mi ki olukoso ayana ina
[04:40.69] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:43.65] Ara banbi jaye oba
[04:45.22] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:48.02] Ara banbi jaye oba
[04:50.34] Sango ijo ti ya fun orogbo
[04:55.78]