[00:06.71] Yawu nigbo gbo wa [00:08.53] Qdot l'oruko mi [00:09.59] Ferrari pheragamoe [00:10.66] Yawu ni gbogbo wa [00:11.63] (Kesa sose) [00:13.64] Yawu ni gbogbo wa [00:14.55] Ole fe m'ole (yawu ni gbogbo wa) [00:16.30] Ko se ni to mo bi olorun (yawu ni gbogbo wa) [00:17.41] Awon ara'bi gan gan won jawa l'ole (yawu ni gbogbo wa) [00:18.45] Won ko'wo wa won f'olopa ko wa (yawu ni gbogbo wa) [00:19.50] A fun won lo'be won fe'yin pe'ran o (yawu ni gbogbo wa) [00:24.05] Ole to ba ri mu ni barawo (yawu ni gbogbo wa) [00:25.63] Ise olosho na self employment (yawu ni gbogbo wa) [00:27.98] L'ola sati ramoni, we must to make money [00:30.41] Hustle kowope, without money life is funny [00:31.83] Ninu aye [00:32.72] Ejo to gbo'wo lo o ma kan anybody [00:35.34] Alaye ko k'aye [00:36.82] Obo gbo'wo lo ko ma kan anybody [00:50.65] Yawu ni gbogbo wa [00:52.59] Olosho gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa) [00:54.00] Aboki gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa) [00:55.48] Eh eh, lecturer gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa) [01:00.69] Mr DJ gbo'wo lo (yawu ni gbogbo wa) [01:01.95] Qdot l'oruko mi [01:03.64] A o'le p'ogberi ba'se p'omo awo [01:04.69] Eni t'ile moba sa ni barawo (gbese) [01:05.85] A n'pe l'ole oun gbo'mo eran jo [01:07.02] O logo o loun m'ogogoro [01:08.09] Ejo ti Barca ba ta messi, player melo lo maku [01:09.06] Eni ta gbe pamo to'n wuko [01:10.22] Tori client mi o soro mo [01:11.43] Wo ro pe'la mi oni yomo [01:13.75] Bokan'wo adan mi,adan mi afi rogi [01:15.69] Kosi bo'se fe je,omo ologo ole jegi [01:16.44] Yawu ni gbogbo wa [01:29.98] Ole fe m'ole (yawu ni gbogbo wa) [01:30.64] Ko se ni tomo bi olorun (yawu ni gbogbo wa) [01:31.74] Awon ara'bi gan gan won jawa l'ole (yawu ni gbogbo wa) [01:45.70] Won ko'wo wa won f'olopa ko wa (yawu ni gbogbo wa) [01:46.39] A fun won lo'be won fe'yin pe'ran o (yawu ni gbogbo wa) [01:53.76] Ole to ba ri mu ni barawo (yawu ni gbogbo wa) [01:56.65] Ise olosho na self employment (yawu ni gbogbo wa) [01:57.62] Baba ijebu je mi efon jemi (yawu ni gbogbo wa) [01:58.74] Obo'n ke inoki'n ke (yawu ni gbogbo wa) [01:59.77] Ole to ji maggi lo ma dana sun (yawu ni gbogbo wa) [02:00.76] Eyi to'n gbowo lo wo'n se "Yes sir" fun (yawu ni gbogbo wa) [02:01.75] Pelu motor to'n dun fafun fafun (yawu ni gbogbo wa) [02:03.50] Omo olomo ni o,ema ran le'won o (yawu ni gbogbo wa) [02:06.77] Agba wa mura o se'we ri (yawu ni gbogbo wa) [02:07.51] Olode ologun ologbon lo'lode o (yawu ni gbogbo wa) [02:08.59] Edakun ejo ka tun'wa ara wa se o (yawu ni gbogbo wa) [02:09.56] Awon ka'n ka pata lo tokun tokun (yawu ni gbogbo wa) [02:10.78] "Baby I love you" na scam o (yawu ni gbogbo wa) [02:11.78] Kesa sose gbese soke (yawu ni gbogbo wa) [02:13.43] Awon eyan sirikuma sirikuma (yawu ni gbogbo wa) [02:14.23] Owo mi da o (yawu ni gbogbo wa) [02:15.78] Artist,DJ,dancer,bouncer (yawu ni gbogbo wa) [02:18.16] Show promoter, kara kata (yawu ni gbogbo wa) [02:19.24] Yawu ni gbogbo wa [02:20.46]